Lati dasi nko lakoko n'le, pataki ti a ba ronu nipa asise ti a le bapade, a fe ko rorun fun awon ilowosi akoko lati le dasi ise agbese lakoko, ise agbese yi a ko yin be ese le se, e tele ilana ni isalẹ
to ba le lo pipaṣẹ, awon ona mi re.
e fi git sori ẹrọ install it.
orita ibi ipamọ yii, e te ' fork bọtini' ni oke oju iwe yi, e leyi a fun yin ni daako ni accounti yin
oya e de ibi ipamọ yi si account yin, e lo si githubu accounti yin, e te 'clone botini, ke wa te 'copy to clipboard' .
e sii ebute in ero ise yin, e te pipaṣẹ to be a labe oro yi si:
git clone "ọna asopọ ' te daakọ"
ibi, "ọna asopọ ' te daakọ" (lai awọn ' quote iṣmiṣ) lo je ono asopo ti e dide ibi ipamo (e dide ibi ipamo ise igbesi). e wo awon atono ti tele to n be loke
oye ko ri bi:
git clone https://github.com/oruko yin/first-contributions.git
ibi oruko yin
ni oruko githubu accounti yin. ni bi yi en didako awon akoonu ' first-contributions repository in GitHubu' si ero ise yin.
seda eka si ero, amo ko to sebe te pipaṣẹ yi si ibe
cd first-contributions
oya seda eka si pelu ' git checkout
pipase:
git checkout -b <oruko to fe so eka to fe seda>
fun apere:
git checkout -b add-luke-oliff
(kon se dadun ki e lo "add", amo o daa fun irun nnkan bayii)
oya shi faili Contributors.md
ninu olootu ọrọ, fi oruko re mo awon oruko to 'n wan be, ma fe se akoko tabi igbeyn, fi si arin.
to ba te pipase git status
si ebute re, wa re awon ayipada ti ose
fi won mo eka ti ode pelu pipase yii git add
:
git add Contributors.md
oya dawon papop pelu pipase yi git commit
:
git commit -m "Add <oruko githubu account yin> to Contributors list"
yi <oruko githubu account yin>
pada si oruko re.
te pipase yi git push
:
git push origin <oruko eda ti e se>
yi <oruko eda ti e se>
pada si orku e da ti ese ni ibere
Ti o ba lọ t' yer ibi ipamọ lori GitHub, iwọ yoo ri a Compare & pull request
botini. te botini yen.
oya fi silẹ.
To ba ya a ma so gbogo yipada ti e se papo, e o gba iwifunni lori imeeli yin
Ku ise oti pari boṣewa bisesenlo fork -> clone -> edit -> PR bisesenlo ti o ma bapade ni ise asowopo
Ṣe ayẹyẹ ilowosi yer 'ki o pin pẹlu' awọn ọkan ati awọn ọmọlẹyin nipasẹ lilọ’ si web app.
Ẹ lè darapọ̀ mọ́ àwọn òṣìṣẹ́ òṣìṣẹ́ wa tí kò já fáfá tí ẹ bá nílò ìrànlọ́wọ́ èyíkéyìí tàbí kí ẹ lè gba àlọ́ kankan. Darapo.
Bayi jẹ ki a bẹrẹ pẹlu' idasi' t' awọn iṣẹ akanṣe miiran. A ti ṣe akojọpọ awọn iṣẹ akanṣe pẹlu awọn ọran irọrun ti o le bẹrẹ. Ṣayẹwo awon re.
GitHub Desktop | Visual Studio 2017 | GitKraken | Visual Studio Code | Atlassian Sourcetree | IntelliJ IDEA |